Ipele to nira:
Tẹ́ ibi lati ka itọni
- Fi ọrọ Geesi we eda ọrọ rẹ ni Yoruba
- Lati safiwe, tẹ odo to wa lẹba ọrọ Geesi, ki o si tun tẹ odo to sunmọ eda rẹ ni ede Yoruba
- Tẹ bọtini to wa labẹ idanwo yi lati wo iye to gba
- Sun siwaju lati ipele ikarun si omiran
- Ipele marun lo wa.Ri daju wipe o pari gbogbo wọn!
Bawo lo se gbọ Yoruba si?
Oni ni ayajọ ede abinibi lagbaye, akori fun ọdun 2019 ni '''Ede abinibi se pataki fun idagbasoke, alaafia ati ipẹtu saawọ''
-
O rorun (awọn eranko)
-
Bat - Adan
-
Camel - Rakunmi
-
Cow - Maalu
-
Ostrich - Ogongo
-
Lizard - Alangba
-
Swan - Pẹpẹyẹ odo
-
Tiger - Ẹkun
-
Bat - Adan
-
Ko nira
-
Five Hundred - Ẹẹdẹgbẹta
-
Fifty - Aadọta
-
Seven Million - Miliọnu meje
-
Five Thousand - Ẹgbẹrun marun
-
Twenty Five - Marundinlọgbọn
-
Thirty Five - Marundinlogoji
-
Seventy Five - Marundinlọgọrin
-
Five Hundred - Ẹẹdẹgbẹta
-
O nira (omi)
-
Ocean - Okun
-
Lake - Adagun odo
-
River - Odo
-
Pond - Adagun odo kekere
-
Stream - Odo to n san
-
Dam - Adagun odo omi ẹrọ
-
Spring - Odo kekere to n san
-
Ocean - Okun